Numeri 1:17 - Yoruba Bible17 Mose ati Aaroni pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ ní ọjọ́ kinni oṣù keji, Sien die hoofstukBibeli Mimọ17 Ati Mose ati Aaroni mú awọn ọkunrin wọnyi ti a pè li orukọ: Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní17 Mose àti Aaroni mú àwọn ènìyàn tí a dárúkọ wọ̀nyí Sien die hoofstuk |