Marku 5:8 - Yoruba Bible8 (Nítorí Jesu tí ń sọ pé kí ẹ̀mí èṣù náà jáde kúrò ninu ọkunrin náà.) Sien die hoofstukBibeli Mimọ8 Nitoriti o wi fun u pe, Jade kuro lara ọkunrin na, iwọ ẹmi aimọ́. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Nítorí tí Ó wí fún un pé, “Jáde kúrò lára ọkùnrin náà, ìwọ ẹ̀mí àìmọ́!” Sien die hoofstuk |