Marku 4:3 - Yoruba Bible3 “Ẹ fi etí sílẹ̀! Ọkunrin kan jáde lọ láti fúnrúgbìn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ3 Ẹ fi eti silẹ; Wo o, afunrugbin kan jade lọ ifunrugbin; Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní3 “Ẹ fi etí sílẹ̀! Ní ọjọ́ kan, afúnrúgbìn kan jáde lọ láti lọ fúnrúgbìn rẹ̀. Sien die hoofstuk |