Marku 2:28 - Yoruba Bible28 Nítorí náà, Ọmọ-Eniyan ni Oluwa ohun gbogbo ati ti Ọjọ́ Ìsinmi pẹlu.” Sien die hoofstukBibeli Mimọ28 Nitorina Ọmọ-enia li oluwa ọjọ isimi pẹlu. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní28 Nítorí náà Ọmọ Ènìyàn ni Olúwa ọjọ́ ìsinmi pẹ̀lú.” Sien die hoofstuk |