Esteri 9:11 - Yoruba Bible11 Ní ọjọ́ náà, wọ́n mú ìròyìn iye àwọn tí wọ́n pa ní Susa wá fún ọba. Sien die hoofstukBibeli Mimọ11 Li ọjọ na a mu iye awọn ti a pa ni Ṣuṣani ãfin wá siwaju ọba. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Ní ọjọ́ náà gan an ni a mú iye àwọn tí a pa ní ilé ìṣọ́ ti Susa wá fún ọba. Sien die hoofstuk |