Esteri 6:7 - Yoruba Bible7 Nítorí náà, ó dá ọba lóhùn pé, “Báyìí ni ó ṣe yẹ kí á dá ẹni tí inú ọba dùn sí lọ́lá: Sien die hoofstukBibeli Mimọ7 Hamani si da ọba lohùn pe, ọkunrin na ẹniti inu ọba dùn si lati bù ọlá fun. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní7 Nítorí náà Hamani dá ọba lóhùn pé, “Fún ọkùnrin tí inú ọba dùn sí láti dá lọ́lá, Sien die hoofstuk |