Eksodu 4:12 - Yoruba Bible12 Nítorí náà, lọ, n óo sì wà pẹlu rẹ, n óo sì máa kọ́ ọ ní ohun tí o óo sọ.” Sien die hoofstukBibeli Mimọ12 Njẹ lọ nisisiyi, emi o si pẹlu ẹnu rẹ, emi o si kọ́ ọ li eyiti iwọ o wi. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Lọ nísinsin yìí, èmi yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti sọ̀rọ̀. Èmi yóò sì kọ́ ọ ni ohun ti ìwọ yóò sọ.” Sien die hoofstuk |