Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 3:3 - Yoruba Bible

3 Mose bá wí ninu ara rẹ̀ pé, “N óo súnmọ́ kinní yìí, mo fẹ́ wo ohun ìyanu yìí, ìdí tí iná fi ń jó tí igbó kò sì fi jóná.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

3 Mose si wipe, Njẹ emi o yipada si apakan, emi o si wò iran nla yi, ẽṣe ti igbẹ́ yi kò run.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Nígbà náà ni Mose sọ pé, “Èmi yóò lọ wo ohun ìyanu yìí, ìdí tí iná kò fi jó igbó run.”

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 3:3

Volg ons:

Advertensies


Advertensies