Eksodu 2:4 - Yoruba Bible4 Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obinrin dúró ní òkèèrè, ó ń wo ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí i. Sien die hoofstukBibeli Mimọ4 Arabinrin rẹ̀ si duro li òkere, lati mọ̀ ohun ti yio ṣe ọmọ na. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Arábìnrin rẹ̀ dúró ni òkèèrè láti wo ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí ọmọ náà. Sien die hoofstuk |