Rutu 1:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Nígbà tí Naomi rí i wí pé Rutu ti pinnu láti tẹ̀lé òun kò rọ̀ láti padà mọ́. Sien die hoofstukYoruba Bible18 Nígbà tí Naomi rí i pé Rutu ti pinnu ninu ọkàn rẹ̀ láti bá òun lọ, kò sọ ohunkohun mọ́. Sien die hoofstukBibeli Mimọ18 Nigbati on ri pe o ti pinnu rẹ̀ tán lati bá on lọ, nigbana li o dẹkun ọ̀rọ ibá a sọ. Sien die hoofstuk |