Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Numeri 5:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 Àlùfáà yóò sì bu erùpẹ̀ ilẹ̀ àgọ́ sínú omi mímọ́ tó bù láti ìkòkò amọ̀,

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

17 yóo da omi mímọ́ sinu àwo kan, yóo bù lára erùpẹ̀ ilẹ̀ Àgọ́ Àjọ sinu omi náà.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

17 Ki alufa ki o si bù omi mimọ́ ninu ohun-èlo amọ̀ kan; ati ninu erupẹ ti mbẹ ni ilẹ agọ́ ni ki alufa ki o bù, ki o si fi i sinu omi na:

Sien die hoofstuk Kopieer




Numeri 5:17

Volg ons:

Advertensies


Advertensies