Numeri 4:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 “Ka iye àwọn ọmọ Merari nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn. Sien die hoofstukYoruba Bible29 OLUWA sọ fún Mose pé, “Ka iye àwọn ọmọ Merari ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ29 Ati awọn ọmọ Merari, ki iwọ ki o kà wọn gẹgẹ bi idile wọn, nipa ile baba wọn; Sien die hoofstuk |