Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Numeri 3:50 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

50 Mose sì gba egbèje ṣékélì ó dín márùn-dínlógójì (1,365) gẹ́gẹ́ bí iye ṣékélì ibi mímọ́ lọ́wọ́ àkọ́bí àwọn ọmọ Israẹli.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

50 Owó tí ó gbà jẹ́ egbeje ìwọ̀n ṣekeli fadaka ó dín marundinlogoji (1,365), gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n ṣekeli tí wọn ń lò ní ibi mímọ́.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

50 Lọwọ awọn akọ́bi awọn ọmọ Israeli li o gbà owo na; egbeje ṣekeli o din marundilogoji, gẹgẹ bi ṣekeli ibi mimọ́:

Sien die hoofstuk Kopieer




Numeri 3:50

Volg ons:

Advertensies


Advertensies