Numeri 2:7 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní7 Ẹ̀yà Sebuluni ni yóò tẹ̀lé e. Olórí Sebuluni ni Eliabu ọmọ Heloni. Sien die hoofstukYoruba Bible7 Kí ẹ̀yà Sebuluni pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Isakari. Eliabu ọmọ Heloni ni yóo jẹ́ olórí wọn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ7 Ati ẹ̀ya Sebuluni: Eliabu ọmọ Heloni yio si jẹ́ olori awọn ọmọ Sebuluni: Sien die hoofstuk |