Numeri 2:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Ẹ̀yà Naftali ni yóò kàn lẹ́yìn wọn. Olórí Naftali ni Ahira ọmọ Enani. Sien die hoofstukYoruba Bible29 Lẹ́yìn náà ni ẹ̀yà Nafutali; Ahira, ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí wọn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ29 Ati ẹ̀ya Naftali: Ahira ọmọ Enani yio si jẹ́ olori awọn ọmọ Naftali: Sien die hoofstuk |