Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Numeri 1:38 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

38 Láti ìran Dani: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ọmọ ogún ọdún sókè, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

38 Ninu ẹ̀yà Dani, àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

38 Ti awọn ọmọ Dani, iran wọn, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun;

Sien die hoofstuk Kopieer




Numeri 1:38

Volg ons:

Advertensies


Advertensies