Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Numeri 1:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Láti ìran Reubeni tí í ṣe àkọ́bí Israẹli: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn, lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

20 Ninu ẹ̀yà Reubẹni, tíí ṣe àkọ́bí Israẹli, àwọn tí wọ́n jẹ́ ẹni ogún ọdún sókè, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

20 Ati awọn ọmọ Reubeni, akọ́bi Israeli, iran wọn, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, nipa ori wọn, gbogbo ọkunrin lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun;

Sien die hoofstuk Kopieer




Numeri 1:20

Volg ons:

Advertensies


Advertensies