Marku 7:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Nítorí pé láti inú ọkàn ènìyàn ni àwọn èrò búburú wọ̀nyí ti ń jáde wá: àgbèrè, olè, ìpànìyàn, panṣágà, Sien die hoofstukYoruba Bible21 Nítorí láti inú ọkàn eniyan ni ète burúkú ti ń jáde: ìṣekúṣe, olè jíjà, ìpànìyàn, Sien die hoofstukBibeli Mimọ21 Nitori lati inu, lati inu ọkàn enia ni iro buburu ti ijade wá, panṣaga, àgbere, ipania, Sien die hoofstuk |