Marku 6:54 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní54 Wọ́n jáde kúrò nínú ọkọ̀. Àwọn ènìyàn tó wà níbẹ̀ rí Jesu, wọ́n sì dá a mọ̀ ọ́n. Sien die hoofstukYoruba Bible54 Bí wọ́n ti jáde kúrò ninu ọkọ̀, lẹsẹkẹsẹ àwọn eniyan mọ̀ wọ́n. Sien die hoofstukBibeli Mimọ54 Bi nwọn si ti njade lati inu ọkọ̀ wá, lojukanna nwọn si mọ̀ ọ, Sien die hoofstuk |