Marku 6:47 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní47 Nígbà tí ó di alẹ́, ọkọ̀ wà láàrín Òkun, òun nìkan sì wà lórí ilẹ̀. Sien die hoofstukYoruba Bible47 Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wà ninu ọkọ̀ ní ààrin òkun, òun nìkan ni ó kù lórí ilẹ̀. Sien die hoofstukBibeli Mimọ47 Nigbati alẹ si lẹ, ọkọ̀ si wà larin okun, on nikan si wà ni ilẹ. Sien die hoofstuk |