Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 6:36 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

36 “Rán àwọn ènìyàn wọ̀nyí láti lọ sí àwọn abúlé àti ìlú láti ra oúnjẹ fún ara wọn.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

36 Jẹ́ kí àwọn eniyan túká, kí wọn lè lọ sí àwọn abà ati abúlé tí ó wà yíká láti ra oúnjẹ fún ara wọn.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

36 Rán wọn lọ, ki nwọn ki o le lọ si àgbegbe ilu, ati si iletò ti o yiká, ki nwọn ki o le rà onjẹ fun ara wọn: nitoriti nwọn kò li ohun ti nwọn o jẹ.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 6:36

Volg ons:

Advertensies


Advertensies