Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 6:27 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

27 Nítorí èyí, ọba rán ẹ̀ṣọ́ kan, ó fi àṣẹ fún un pé, kí ó gbé orí Johanu wá. Ọkùnrin náà sì lọ, ó bẹ́ Johanu lórí nínú túbú.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

27 Lẹsẹkẹsẹ ọba rán ọmọ-ogun kan, ó pàṣẹ fún un kí ó gbé orí Johanu wá. Ó bá lọ, ó bẹ́ ẹ lórí ninu ilé ẹ̀wọ̀n.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

27 Lọgan ọba si rán ẹṣọ́ kan, o fi aṣẹ fun u pe, ki o gbé ori rẹ̀ wá: o si lọ, o bẹ́ Johanu lori ninu tubu.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 6:27

Volg ons:

Advertensies


Advertensies