Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 6:26 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

26 Inú ọba sì bàjẹ́ gidigidi, ṣùgbọ́n nítorí àwọn ìbúra rẹ, àti nítorí àwọn tí ó bá a jókòó pọ̀, kò sì fẹ́ kọ̀ fún un.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

26 Inú ọba bàjẹ́ pupọ, ṣugbọn nítorí ó ti ṣe ìlérí pẹlu ìbúra lójú àwọn tí ó wà níbi àsè, kò fẹ́ kọ̀ fún un.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

26 Inu ọba si bajẹ gidigidi; ṣugbọn nitori ibura rẹ̀, ati nitori awọn ti o bá a joko pọ̀, kò si fẹ ikọ̀ fun u.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 6:26

Volg ons:

Advertensies


Advertensies