Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 6:25 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

25 Ọmọbìnrin yìí sáré padà wá sọ́dọ̀ Herodu ọba. Ó sì wí fún un pé, “Mo ń fẹ́ orí Johanu Onítẹ̀bọmi nísinsin yìí nínú àwopọ̀kọ́.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

25 Ọmọbinrin náà yára lọ sí ọ̀dọ̀ ọba, ó wí pé, “Mo fẹ́ kí o fún mi ní orí Johanu Onítẹ̀bọmi kíákíá, kí wọ́n fi àwo pẹrẹsẹ gbé e wá.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

25 Lojukanna, o si wọle tọ̀ ọba wá kánkan, o bère, wipe, emi nfẹ ki iwọ ki o fi ori Johanu Baptisti fun mi ninu awopọkọ nisisiyi.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 6:25

Volg ons:

Advertensies


Advertensies