Marku 6:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Nítorí náà ni Herodia ṣe ní sínú, òun sì fẹ́ pa á, ṣùgbọ́n kò le ṣe é. Sien die hoofstukYoruba Bible19 Nítorí náà Hẹrọdiasi ní Johanu sinu, ó fẹ́ pa á, ṣugbọn kò lè pa á, Sien die hoofstukBibeli Mimọ19 Nitorina ni Herodia ṣe ni i sinu, on si nfẹ ipa a; ṣugbọn kò le ṣe e: Sien die hoofstuk |