Marku 6:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Wọ́n jáde lọ láti wàásù ìrònúpìwàdà fún àwọn ènìyàn. Sien die hoofstukYoruba Bible12 Bí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila ti ń lọ, wọ́n ń waasu pé kí gbogbo eniyan ronupiwada. Sien die hoofstukBibeli Mimọ12 Nwọn si jade lọ, nwọn si wasu ki awọn enia ki o le ronupiwada. Sien die hoofstuk |