Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 5:43 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

43 Jesu sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn má ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀. Ó sì wí fún wọn kí wọn fún ọmọbìnrin náà ní oúnjẹ.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

43 Jesu wá kìlọ̀ fún wọn gan-an pé kí wọn má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀. Ó ní kí wọn wá oúnjẹ fún ọmọde náà kí ó jẹ.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

43 O si paṣe fun wọn gidigidi pe, ki ẹnikẹni ki o máṣe mọ̀ eyi; o si wipe, ki nwọn ki o fun u li onjẹ.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 5:43

Volg ons:

Advertensies


Advertensies