Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 5:42 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

42 Lẹ́sẹ̀kan náà, ọmọbìnrin náà sì dìde. Ó sì ń rìn, ẹ̀rù sì bà wọ́n, ẹnu sì ya àwọn òbí rẹ̀ gidigidi.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

42 Lẹsẹkẹsẹ ọmọdebinrin náà dìde, ó bá ń rìn, nítorí ọmọ ọdún mejila ni. Ìyàlẹ́nu ńlá ni ó jẹ́ fún gbogbo wọn.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

42 Lọgan ọmọbinrin na si dide, o si nrìn; nitori ọmọ ọdún mejila ni. Ẹ̀ru si ba wọn, ẹnu si yà wọn gidigidi.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 5:42

Volg ons:

Advertensies


Advertensies