Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 5:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Nítorí naà, ọkùnrin yìí padà lọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí ròyìn ní Dekapoli nípa ohun ńlá tí Jesu ṣe fún un. Ẹnu sì ya gbogbo ènìyàn.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

20 Ọkunrin náà lọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí ròyìn ohun tí Jesu ṣe fún un ní agbègbè Ìlú Mẹ́wàá, ẹnu sì ya gbogbo eniyan tí ó gbọ́.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

20 O si pada lọ, o bẹ̀rẹ si ima ròhin ni Dekapoli, ohun nla ti Jesu ṣe fun u: ẹnu si yà gbogbo enia.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 5:20

Volg ons:

Advertensies


Advertensies