Marku 5:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Nígbà náà ni ẹ̀mí àìmọ́ náà bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ Jesu gidigidi, kí ó má ṣe rán àwọn jáde kúrò ní agbègbè náà. Sien die hoofstukYoruba Bible10 Ó bá bẹ̀rẹ̀ sí bẹ Jesu títí pé kí ó má ṣe lé wọn jáde kúrò ní agbègbè ibẹ̀. Sien die hoofstukBibeli Mimọ10 O si bẹ̀ ẹ gidigidi pe, ki o máṣe rán wọn jade kuro ni ilẹ na. Sien die hoofstuk |