Marku 4:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Nígbà tí èso bá gbó tán, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, òun a tẹ dòjé bọ inú ọkà náà, ó sì kórè rẹ̀.” Sien die hoofstukYoruba Bible29 Nígbà tí ó bá gbó tán, lẹsẹkẹsẹ ọkunrin náà yóo yọ dòjé jáde nítorí pé àkókò ìkórè ti dé.” Sien die hoofstukBibeli Mimọ29 Ṣugbọn nigbati eso ba pọ́n tan, lojukanna on a tẹ̀ doje bọ inu rẹ̀ nitori igba ikorè de. Sien die hoofstuk |