Marku 3:14 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní14 Ó yan àwọn méjìlá, kí wọn kí ó lè wà pẹ̀lú rẹ̀, àti kí ó lè rán wọn lọ láti wàásù Sien die hoofstukYoruba Bible14 Ó bá yan àwọn mejila, ó pè wọ́n ní aposteli, kí wọn lè wà pẹlu rẹ̀, kí ó lè máa rán wọn lọ waasu, Sien die hoofstukBibeli Mimọ14 O si yàn awọn mejila, ki nwọn ki o le mã gbé ọdọ rẹ̀, ati ki o le ma rán wọn lọ lati wasu, Sien die hoofstuk |