Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 3:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 Jesu gun orí òkè lọ, ó sì pe àwọn kan tí ó yàn láti wà pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì tọ̀ ọ́ wá.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

13 Lẹ́yìn náà, ó wá gun orí òkè lọ, ó pe àwọn tí ó wù ú sọ́dọ̀, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lọ.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

13 O si gùn ori òke lọ, o si npè ẹnikẹni ti o fẹ sọdọ rẹ̀: nwọn si tọ̀ ọ wá.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 3:13

Volg ons:

Advertensies


Advertensies