Marku 1:39 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní39 Nítorí náà, ó ń kiri gbogbo agbègbè Galili, ó ń wàásù nínú Sinagọgu. Ó sì ń lé àwọn ẹ̀mí àìmọ́ jáde. Sien die hoofstukYoruba Bible39 Ó bá lọ, ó ń waasu ninu àwọn ilé ìpàdé wọn ní gbogbo ilẹ̀ Galili, ó ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde. Sien die hoofstukBibeli Mimọ39 O si nwãsu ninu sinagogu wọn lọ ni gbogbo Galili, o si nlé awọn ẹmi èṣu jade. Sien die hoofstuk |