Marku 1:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tọ̀ Ọ́ lẹ́yìn. Sien die hoofstukYoruba Bible18 Lẹ́sẹ̀ kan náà wọ́n bá fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n ń tẹ̀lé e. Sien die hoofstukBibeli Mimọ18 Lojukanna nwọn si fi àwọn wọn silẹ, nwọn si tọ̀ ọ lẹhin. Sien die hoofstuk |