Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Marku 1:15 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Ó sì kéde wí pé, “Àkókò náà dé wàyí, ìjọba Ọlọ́run kù sí dẹ̀dẹ̀. Ẹ yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ yín, kí ẹ sì gba ìhìnrere yìí gbọ́.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

15 Ó ń wí pé, “Àkókò tó; ìjọba Ọlọrun súnmọ́ ìtòsí. Ẹ ronupiwada, kí ẹ gba ìyìn rere gbọ́.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

15 O si nwipe, Akokò na de, ijọba Ọlọrun si kù si dẹ̀dẹ: ẹ ronupiwada, ki ẹ si gbà ihinrere gbọ́.

Sien die hoofstuk Kopieer




Marku 1:15

Volg ons:

Advertensies


Advertensies