Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Joẹli 1:7 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

7 Ó ti pa àjàrà mi run, ó sì ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi kúrò, ó ti bò èèpo rẹ̀ jálẹ̀, ó sì sọ ọ́ nù; àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ni a sì sọ di funfun.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

7 Wọ́n ti run ọgbà àjàrà mi, wọ́n ti já àwọn ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi, wọ́n ti bó gbogbo èèpo ara rẹ̀, wọ́n ti wó o lulẹ̀, àwọn ẹ̀ka rẹ̀ sì ti di funfun.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

7 O ti pa àjara mi run, o si ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọtọ́ mi kuro, o ti bó o jalẹ, o si sọ ọ nù; awọn ẹ̀ka rẹ̀ li a si sọ di funfun.

Sien die hoofstuk Kopieer




Joẹli 1:7

Volg ons:

Advertensies


Advertensies