Joẹli 1:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní17 Irúgbìn bàjẹ́ nínú ebè wọn, a sọ àká di ahoro, a wó àká palẹ̀; nítorí tí a mú ọkà rọ. Sien die hoofstukYoruba Bible17 Irúgbìn díbàjẹ́ sinu ebè, àwọn ilé ìṣúra ti di ahoro, àwọn àká ti wó lulẹ̀, nítorí kò sí ọkà láti kó sinu wọn mọ́. Sien die hoofstukBibeli Mimọ17 Irugbìn bajẹ ninu ebè wọn, a sọ aká di ahoro, a wó abà palẹ; nitoriti a mu ọ̀ka rọ. Sien die hoofstuk |