Esteri 5:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Ṣùgbọ́n gbogbo èyí kò ì tí ì tẹ́ mi lọ́rùn níwọ̀n ìgbà tí mo bá sì ń rí Mordekai ará a Júù náà tí ó ń jókòó ní ẹnu-ọ̀nà ọba.” Sien die hoofstukYoruba Bible13 Ṣugbọn gbogbo nǹkan wọnyi kò lè tẹ́ mi lọ́rùn, bí mo bá ń rí Modekai, Juu, tí ó ń jókòó ní ẹnu ọ̀nà ààfin ọba.” Sien die hoofstukBibeli Mimọ13 Ṣugbọn gbogbo wọnyi kò di nkankan fun mi, niwọ̀n igbati mo ba ri Mordekai, ara Juda nì, ti o joko li ẹnu ọ̀na ile ọba. Sien die hoofstuk |