Esteri 5:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Hamani tún fi kún un pé, “Kì í ṣe èyí nìkan. Èmi nìkan ni ayaba Esteri pè láti sin ọba wá sí ibi àsè tí ó sè. Bákan náà, ó sì tún ti pè mí pẹ̀lú ọba ní ọ̀la. Sien die hoofstukYoruba Bible12 Hamani tún fi kún un pé “Ayaba Ẹsita kò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni bá ọba wá sí ibi àsè rẹ̀, àfi èmi nìkan. Ó sì ti tún pe èmi ati ọba sí àsè mìíràn ní ọ̀la. Sien die hoofstukBibeli Mimọ12 Hamani si wi pẹlu pe, ani Esteri ayaba kò mu ki ẹnikẹni ki o ba ọba wá si ibi àse ti o ti sè bikoṣe emi nikan; li ọla ẹ̀wẹ li a si tun pè mi pẹlu ọba lati wá si ọdọ rẹ̀, Sien die hoofstuk |