Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Esteri 10:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Àti gbogbo ìṣe agbára àti títóbi rẹ̀, papọ̀ pẹ̀lú ìròyìn títóbi Mordekai ní èyí tí ọba ti gbé e ga, kò ha wà nínú àkọsílẹ̀ ìwé ọdọọdún ọba ti Media àti ti Persia?

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

2 Gbogbo iṣẹ́ agbára ati ipá rẹ̀, ati bí ó ṣe gbé Modekai ga sí ipò ọlá, ni a kọ sinu ìwé ìtàn àwọn ọba Media ati ti Pasia.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

2 Ati gbogbo iṣe agbara rẹ̀, ati ti ipa rẹ̀, ati ìrohin titobi Mordekai, bi ọba ti sọ ọ di nla, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Media ati Persia?

Sien die hoofstuk Kopieer




Esteri 10:2

Volg ons:

Advertensies


Advertensies