Eksodu 6:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili àti Muṣi. Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn. Sien die hoofstukYoruba Bible19 Merari bí ọmọkunrin meji: Mahili ati Muṣi. Àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi nìwọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí arọmọdọmọ wọn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ19 Ati awọn ọmọ Merari; Mahali, ati Muṣi. Wọnyi ni idile Lefi ni iran wọn. Sien die hoofstuk |