Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 5:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Gbogbo wọn sí fọ́n káàkiri ni ilẹ̀ Ejibiti láti sa ìdì koríko tí wọn yóò lò bí ì koríko gbígbẹ fún sísun bíríkì.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

12 Wọ́n bá fọ́n káàkiri gbogbo ilẹ̀ Ijipti láti wá àgékù koríko.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

12 Bẹ̃li awọn enia na si tuka kiri ká gbogbo ilẹ Egipti lati ma ṣà idi koriko ni ipò koriko.

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 5:12

Volg ons:

Advertensies


Advertensies