Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 4:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Aaroni sọ ohun gbogbo tí Olúwa sọ fún Mose fún wọn, ó sì ṣe iṣẹ́ ààmì náà ní ojú àwọn ènìyàn náà.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

30 Aaroni sọ gbogbo ohun tí OLUWA sọ fún Mose fún wọn, ó sì ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu náà lójú gbogbo àwọn àgbààgbà náà.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

30 Aaroni si sọ gbogbo ọ̀rọ ti OLUWA ti sọ fun Mose, o si ṣe iṣẹ-àmi na li oju awọn enia na.

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 4:30

Volg ons:

Advertensies


Advertensies