Eksodu 4:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Mose dáhùn ó wí pé, “Olúwa jọ̀wọ́ rán ẹlòmíràn láti lọ ṣe iṣẹ́ yìí.” Sien die hoofstukYoruba Bible13 Ṣugbọn Mose tún ní, “OLUWA mi, mo bẹ̀ ọ́, rán ẹlòmíràn.” Sien die hoofstukBibeli Mimọ13 On si wipe, Oluwa, emi bẹ̀ ọ, rán ẹniti iwọ o rán. Sien die hoofstuk |