Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 3:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Níbẹ̀ ni angẹli Olúwa ti yọ sí i nínú ọ̀wọ́-iná tí ń jó láàrín igbó. Mose rí i pé iná ń jó nínú igbó ṣùgbọ́n igbó kò run

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

2 Angẹli OLUWA farahàn án ninu ahọ́n iná láàrin ìgbẹ́; bí ó ti wò ó, ó rí i pé iná ń jó nítòótọ́, ṣugbọn igbó náà kò jóná.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

2 Angeli OLUWA si farahàn a ninu ọwọ́ iná lati inu ãrin igbẹ̀: on si wò, si kiyesi i, iná njó igbẹ́, igbẹ́ na kò si run.

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 3:2

Volg ons:

Advertensies


Advertensies