Eksodu 2:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Arábìnrin rẹ̀ dúró ni òkèèrè láti wo ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí ọmọ náà. Sien die hoofstukYoruba Bible4 Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obinrin dúró ní òkèèrè, ó ń wo ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí i. Sien die hoofstukBibeli Mimọ4 Arabinrin rẹ̀ si duro li òkere, lati mọ̀ ohun ti yio ṣe ọmọ na. Sien die hoofstuk |