Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 1:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Wàyí o, Josẹfu àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú,

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

6 Nígbà tí ó yá, Josẹfu kú, gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ náà kú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan títí tí gbogbo ìran náà fi kú tán.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

6 Josefu si kú, ati gbogbo awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo iran na.

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 1:6

Volg ons:

Advertensies


Advertensies