Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 1:22 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

22 Nígbà náà ni Farao pàṣẹ yìí fún gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ pé; “Gbogbo ọmọkùnrin tí a bí ni kí ẹ gbé jù sínú odò Naili, ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ọmọbìnrin ni kí ẹ jẹ́ kí wọn ó wà láààyè.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

22 Farao bá pàṣẹ fún gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Gbogbo ọmọkunrin tí àwọn Heberu bá bí, ẹ máa gbé wọn sọ sinu odò Naili, ṣugbọn kí ẹ dá àwọn ọmọbinrin wọn sí.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bibeli Mimọ

22 Farao si paṣẹ fun gbogbo awọn enia rẹ̀, wipe, Gbogbo ọmọkunrin ti a bí on ni ki ẹnyin gbé jù sinu odò, gbogbo awọn ọmọbinrin ni ki ẹnyin ki o dasi.

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 1:22

Volg ons:

Advertensies


Advertensies