Numeri 6:27 - Bibeli Mimọ27 Bayi ni nwọn o fi orukọ mi sara awọn ọmọ Israeli; emi o si busi i fun wọn. Sien die hoofstukYoruba Bible27 “Bẹ́ẹ̀ ni wọn óo fi orúkọ mi súre fún àwọn ọmọ Israẹli, n óo sì bukun wọn.” Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní27 “Báyìí ni wọn ó ṣe fi orúkọ mi sára àwọn ọmọ Israẹli, Èmi ó sì bùkún wọn.” Sien die hoofstuk |